Thursday, 24 November 2016

ARA KENGE(Wonder shall never end)

Ara kenge nile 'bikan(Wonders shall never end... Ewo ni ka ti pe ara tawon wonyi tun n da o...e dakun se jangirofa epo moto ni?

alo apagbe(fables)

Ni igba laelae, ijapa ati igbin je ore korikosun. Gege bi a ti se mo... ijapa tiroko oko yannibo je ologbon ewe. Eredi ibadoreepo re pelu igbin ni lati le maa ri je lara re. Arijenimodaru eda ni oko yannibo. Ijapa gba igbin ore re ni imoran pe ki awon di jo maa se ode papo ninu igbo, igbin si gba imoran re wole. Igbin damoran pe ki awon maa de ebiti pa eran , ki awon mejeeji si jo maa ji wa woo ni kutu ai ni oroowuro. Ijapa si gba bee. Won de ebiti nla kan sinu igbo, won si se adehun laarin ara won pe eran ti ebiti naa ba mu loojo, enikan ni yoo gbe e lo sile, eran ti o ba si tun mu nijo keji yoo je ti enikeji. Bi ile ti mo ni ojo keji, won ti ji de idi ebiti. Nigbati won woo, won rii pe o ti mu eku. Igbin mu eku naa, sugbon ijapa taku pe oun ni o ni eto lati koko mu eran ti ebiti pa. Igbin ko binu, o fun ijapa ni eku naa, o si so, fun un pe ki o maa mu un lo, nigba ti ebiti ba pa okete ni ola, oun yoo gbee. Ijapa roo titi, o rii pe, okete tobi ju eku lo, o si gba fun igbin lati maa mu eku naa lo, nigba ti o ba di ola, oun yoo gbe okete. Igbin si lo se eku je nile ni tire. Nje ebiti tile gbe eran miiran bi? Se eyin si ranti itan alo apagbe yii? E dakun e bawa pari re. Leyin naa ki e so awon eko ti a ri fayo ninu itan naa. E seun.

Ijanba Ina nile eko gbogbonise Yaba.....Fire outbreak in Yabatech !

YABATECH: Fire destroys 20 rooms in female hostel, academic activities suspended fire-destroys-20-rooms-female-hostel-academic-activities-suspended/Lagos – An early morning inferno on Wednesday destroyed 20 rooms in a female hostel at the Yaba College of Technology in Lagos. The fire broke out at a wing of the top floor of the Bakassi female hostel in the school. It was gathered that the inferno started at about 5.20 a.m. when the school generator was switched on after a power outage. Three students sustained injuries as a result of commotion that ensued when the inferno started. The injured students were rushed to the Federal Medical Centre, Yaba and the General Hospital, Randle Avenue, Surulere. Dr Ismail Badmus, the Head of Department of the Fire Service in the school, confirmed the incident. He said that no life was lost, but that some students were injured and taken to government hospitals for treatment. “The incident happened at Bakassi Female hostel which is a two-wing two-storey building. It was the top floor of one of the two wings of the hostel. “There was no life lost, but there were some injuries. “We lost a lot of students’ items like laptops, phones, books and mattresses. You know it is residential hostel; many combustibles are there, which readily catch fire,’’ Ismail told NAN. He said that the fire was combated with the combined efforts of the college’s fire service department, National Emergency Management Agency (NEMA), Lagos State Emergency Management Agency, Lagos State Fire Service and the State Response Unit. Meanwhile, authorities of the college have suspended all academic activities till further notice following the fire outbreak. The Rector of the college, Dr Margaret Ladipo, called on the college community to remain calm, promising that the management would find ways of soothing the pains caused by the accident. “Sequel to the unfortunate fire incident at the Bakassi hostel early this morning, the management has suspended all academic activities till further notice. “By this notice, all examinations and lectures, especially scheduled for today, have been put on hold while the college attends to the exigency. “The management regrets the misguided and outright falsehood on the social media and calls to certain radio stations that there was no water on campus to put out the fire,’’ Ladipo said in a statement issued by Mr Charles Oni, Head of Public Relations Unit. Read more at: http://www.vanguardngr.com/2016/11/yabatech-fire-destroys-20-rooms-female-hostel-academic-activities-suspended/